Home LÁGBO ÀRÍYÁ Idi ti a ko fi da si oro Yetunde Akilapa to n jale – Baba Latin
LÁGBO ÀRÍYÁ - Orisirisi - December 30, 2018

Idi ti a ko fi da si oro Yetunde Akilapa to n jale – Baba Latin


Olori egbe awon osere ti a mo si TAMPAN, Alagba Bolaji Amusan, ti opo eniyan mo si Baba Latin, ti se alaye idi ti awon ko fi le da si oro okan lara awon osere fiimu ti oruko re n je Yetunde Akilapa.
Omobinrin naa ni won maa n mu fun ole jija lojoojumo, ti oro re si ti n ru awon eniyan kan loju.
Won fe mo bi asasi ni tabi ogun idile.
Baba Latin, eni to sese di aare TAMPAN, ni awon ko le se nnkan kan lori oro Yetunde tori kii se omo egbe naa.
Baba Latin wa seleri pe oun yoo seto irepo ati idagbasoke laarin awon alariya.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…