Home Orisirisi Àwọn Ọlọ́pàá yapa sílé Melaye
Orisirisi - December 30, 2018

Àwọn Ọlọ́pàá yapa sílé Melaye

Iroyin yajoyajo to te iroyin owuro lowo bayii ni pe awon olopaa tun lo po sii nile Senato Dino Melaye, to n soju ipinle Kogi.
Ti a ko ba gbagbe, Seneto yii ni awon olopaa fi esun ipaniyan kan ti won si ranse sii ki o foju kan awon ni ago olopaa to wa ni Kogi. Nigba ti awon olopaa ko ri Melaye ni won ba di papa mora lo si ile re lati ojo jimo.
Oni ogbon ojo, osu kejila ni won ba tun ko awon olopaa kun awon olopaa to n so ile Senato naa ni Maitama to wa ni ilu Abuja.
Dino Melaye ba awon oniroyin telifison CHANNELS soro ni ijeeta pe oun o ki n se odaran, oun maa yoju ni ose ti o bere ni oni si ago won. O ni oun ko si ninu ile ti awon olopaa wa be si ni awon olopaa ni inu ile naa lo wa. Awon kan ni boya nitori ipo re lawujo ni ko je ki awon olopaa fo ilekun wole lati fi owo sinkun ofin muu.
Gbogbo araye lo n reti ohun to maa sele nitori pe “aláàárẹ ò kì ń rá sínú ilé …”.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…