Asiko ti to ki obinrin di Aare Naijiria – Omotola
Bo tile je pe osere fiimu to je ilumomika, Omotola Jalade-Ekeinde, ko se oselu, o ti so pe bi Naijiria ba ni Aare to je obinrin bayii kii se ohun to buru.
O ni awon obinrin ti n gbe nnkan ribiribi se, to si je pe
awon kan ninu won gan-an ni won n se olori ile won.
Bakan naa, Omotola so pe awon obinrin ti n di awon ile ise nla nla mu.
Fun idi eyi, o ni ko si oro ninu ki a maa so pe obinrin ko le se Aare.
Mi ò gba owó oṣù fún ọdún mẹ́jọ mi gẹ́gẹ́ bíi gómìnà Ọ̀sun
Mi ò gba owó oṣù fún ọdún mẹ́jọ mi gẹ́gẹ́ bíi gómìnà Ọ̀sun Ọrẹ Òtítọ́jù Minisita ọrọ abẹle…