Home LÁGBO ÀRÍYÁ Ohun Salawa Abeni n ja tantan ni I-Impact
LÁGBO ÀRÍYÁ - December 25, 2018

Ohun Salawa Abeni n ja tantan ni I-Impact

Gbogbo awon aladugbo ile igbafe I-Impact, eyi to wa ni Ibafo, ni won mo pe akorin waka, Salawa Abeni, wa nibe lojo Sunday nigba to sere da awon eniyan lara ya.
Koda, awon to wa ni Magboro ati Wawa gan-an, ti gbogbo won wa legbee popona morose Lagos-Ibadan Expressway, ni won mo pe Selilawa baa won lalejo.
Bi o tile je pe o ti pe to ti n korin, oun re sit un la gaara bi ti akuko to ko jaye ko jorun ni.
Eyi mu ki awon ti ko si ni I-Impact gan-an gbadun ere re gege bii ti awon to rowo wole.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…