Home LÁGBO ÀRÍYÁ Oni ni Kabirah n se wolimo!
LÁGBO ÀRÍYÁ - December 23, 2018

Oni ni Kabirah n se wolimo!

Waasi, waka, adura ati awejewemu n lo lowo bayii ni Ijesatedo, ni ilu Eko, nibi ti osere fiimu, Kabirah Kafidipe, ti n se wolimo lowo.
Musulumi ti kii fie sin sere ni Kabirah, bi o tile je pe alariya ni.
Gbogbo fiimu to maa n se naa, kii se onisekuse. Kii bora sile, bee ni iwa omoluabi kii jinna si i.
Boya elesyi naa lo yori sib o se lo ke Alukurani to wa n se Wolimo lonii.
IROYIN OWURO yoo maa je ke gbo bo se loni ilu Eko.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…