Home LÁGBO ÀRÍYÁ Joke Silva fun Funke Akindele ni oruko miran
LÁGBO ÀRÍYÁ - Orisirisi - December 23, 2018

Joke Silva fun Funke Akindele ni oruko miran


Pelu bi idunnu se subu layo ninu ebi Funke Akindele, lori bi o se yi ibeji lanti-lanti sile fun olow ori re, Rasheed Bello, opo eniyan lo m ba a yo, ti won n ki arabinrin naa ku oriire o.
Bi eni kankan ko tie so o sita, won mo pe oro re t’ope, o jope lo.
Won mo pe Olorun lo ba a p’ota lenu mo, paapaa lori awon ariran kan ti won ni ko ni seese fun un.
Nigba ti osere fiimu pataki, Joke Silva, n ki Funke ku oriire, o pe e ni orisiirisii oruko aladun.
O pe e ni Olufunke, Obafunke, Oyefunke ati Iyafunke, to sib a kan saara si Olorun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…