Home LÁGBO ÀRÍYÁ Ila oju mi ti mu ire ba mi lopolopo – Sanyeri
LÁGBO ÀRÍYÁ - December 22, 2018

Ila oju mi ti mu ire ba mi lopolopo – Sanyeri

Gbajugbaja alawada, Olaniyi Sanyeri, ti se alaye pe ila oju oun ti mure ba oun pupo ninu ere onise ati fiimu.
O ni o maa n fun oun laaye lati kopa ninu awon ere apanilerin-in, ti eni kan ko si maa n ba oun du iru awon ipo bee.
O ni oun kiii ba won da si ere onifee (romantic) tori oun mo pe oun kii se arewa.
Sugbon ila oju re ti pese opo ipa miiran fun oun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…