Home iroyin O se, wọn ka ọkan eniyan mọ babalawo lọwọ
iroyin - Orisirisi - December 21, 2018

O se, wọn ka ọkan eniyan mọ babalawo lọwọ

Babalawo kan to je omo odun marun-un din laadrun-unn – 85 years – ti wa ninu ahamo awon olopaa ni Ipinle Eko bayii, tori won ba ebo leru re.
Okan omo eniyan ni won ba ninu ile re, ni Abeokuta.
O ni eni kan lo wa fun oun ni okan naa, to ni ki oun ba oun fi se oogun owo.
O ni eni na ti oruko re n je Abiodun wa ba oun lati Ipinle Kwara, sugbon ko pada wa mo.
Sugbon sa o, awon olopaa ni okunrin naa ti pa eniyan meji kan, to si sin won sile re, tele.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara Orẹ Òtítọ́jù Egbìnrìn ọ̀tẹ̀ bí a ṣe ń pà…