Home Orisirisi O ma se o! Okunrin kan ku ninu idije ibalopọ pẹlu ololufẹ
Orisirisi - December 20, 2018

O ma se o! Okunrin kan ku ninu idije ibalopọ pẹlu ololufẹ

Gbegede ti gbina ni ilu Eko nibi ti okunrin kan ti n ba ololufe re se idije ibalopo, eyi ti awon oloyinbo n pe ni sex competition.
Ilu Ikotun ninu oteeli kan ni a gbo pe surutu naa ti waye.
Iroyin fi ye wa pe okunrin kan ti won pe oruko re ni Davy ati ololufe re, Loveth, ni won jo leri-leka si ara won pea won fe mo eni ti yoo koko re laarin awon.
Koda, gege bi iwe iroyin THE GUARDIAN se so, a gbo pe okunrin naa so pe oun maa fun Loveth ni N50,000 ti o ba pa oun layo
Sugbon ni liana asayan oro Yoruba to ni olomi lo ma re, igba ti won se kinni naa to wa di eleekeje ni Davy subu lule to si tibe lo si orun alakeji
Awon olopaa Ikotun ni won o ko wahala naa lo ba, to si je pe keesi ti wa ni Panti bayii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…