Home Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ Gomina Ayade ranti igba to n wa tasin
Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - December 20, 2018

Gomina Ayade ranti igba to n wa tasin

Aworawo kan ti ise, ibi ori eni ba ni a ma de, a ko ni sai debe dandan.
Eyi lo fa a ti awon Yoruba tun fi maa n so pe oni la ri, Yarabi lo mo ola.
Oro ti Gomina Ipinle Cross River, Ojogbon Ben Ayade, so lanaa Alaaruba lo fa arokan yii.
O ni nigba kan ri, awako tasin ni oun.
O so eyi ni Calabar nigba to n se ipade pelu pelu egbe awon onimoto ero Ipinle naa.
O ni oun ko le foju tembelu won tori oun naa mo bi oun se bere.
Eyi fa ki awon onimoto naa rojo atewo le e lori.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…