Owolabi Ajasa kare lae, o pari NYSC
Orin to ye ki a maa ko fun osere fiimu Owolabi Ajasa, bayii ni, ‘Mo gba fun e/ Omo ni e/ O ti doga’.
Idi ni iwi pe o ti pari eto agunbaniro NYSC re bayii.
Pelu idunnu lo se gbe foto satifikeeti re soke gege, to si bu erin da si eeke.
O ye ki inu Ajasa, eni to saaba maa n se olopaa ninu fiimu, dun ju bayii lo – tori wi pe oun ni eni akoko ti o koko pari eko yunifasiti ninu iran won.
Eyi tumo si pe oun naa lo koko kopa ninu eto agunbaniro.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…