Home iroyin Nnkan nla, oro ASUU ati ijoba ko tii lojutu o
iroyin - December 19, 2018

Nnkan nla, oro ASUU ati ijoba ko tii lojutu o

Aare egbe awon olukoni ni awon yunifasiti wa – Academic Staff Union on Universities – Ojogbon Biodun Ogunyemi, ti so pe ijoba ko tii gbe igbese kan gunmo lori oun ti awon n ja si.
Lati bii ose mefa seyin ni awon ASUU ti da ise sile, ti awon omo ile iwe si w anile.
Ogunyemi ni ijoba Apapo kan n pooyi ran-in ni, won ko se ipinnu kankna lori ohun ti awon gbe siwaju re la tri i pe ayipada yoo baa won yunifasiti wa.
Eyi tumo sip e idasesile naa si n lo ni pereu, ti asiko awon akekoo si tubo n sofo.
Ohun to tun buru ju ni pe awon akekoo poli naa w anile latari bi awon oluko ibe naa se da ise sile.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…