Home LÁGBO ÀRÍYÁ Alihamudulilai! Kabirah Araparegangan fẹ se wolimọ
LÁGBO ÀRÍYÁ - Orisirisi - December 19, 2018

Alihamudulilai! Kabirah Araparegangan fẹ se wolimọ

Gbajgbaja onifiimu, Kabirah Kafidipe, ti opo eniyan mo si Araparegangan, wa ni irokuku-rokeke bayii, latari bo se n palemo fun eto Wolimo to fe se ni ojo Sunday.
Ilu Eko ni eto naa yoo ti waye, ni Monbitu Sa’adatil-Il-Miyat Arabic and Islamic Institute, ni Ijesatedo, nibi to ti ko eko Kuraani naa.
Arpa ni inu oun dn gidi pe Olorun fun oun ni okun ati agbara lati kese-jari lori eto eko naa.
Gege bi o ti so, alariya tabi eni Kankan ko gbodo so pe tori iru ise kan ti oun n se, ko wa so oro ti Olorun nu.
O ni eyi ko bojumu rara.
Opo awon gbajumo egbe Kabirah la gbo pe o maa wa nibe.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…