Home iroyin Jimi Agbaje tun juko ọrọ si Tinubu
iroyin - Orisirisi - December 18, 2018

Jimi Agbaje tun juko ọrọ si Tinubu

Oludije gomina ninu egbe PDP ni Eko, Ogbeni Jimi Agbaje, tun ti ju oko oro si Olori egbe APC, Asiwaju Bola Tinubu.
O ni Tinubu dabi adenimole oba Egypt ti a mo si Pharaoh.
O ni Tinubu da ajaga si awon ara Eko lorun, to si je pe ibi to n bo ni oun oo fit u won sile.
Lojo Monday, Tinubu fi Agbaje se yeye, nipa siso oro itusile ‘freedom’ to ni oun fe fun awon ara Eko di yeye.
Asiwaju ni eni to ba fe se freedom lo lo ko ise tailor tabi foganaisa.
O ni to ba wa kose pari, awon yoo se freedom fun un.
Eyi ni Agbaje soro le loeri ninu atejade kan to se lonii.
O ni loooto ni Ipinle Eko wa ninu ide, sugbon egbe PDP yoo ko won jade.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…