Home iroyin Awuyewuye lori satifikeeti Dapo Abiodun
iroyin - Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - December 16, 2018

Awuyewuye lori satifikeeti Dapo Abiodun

Wahala to n de ba egbe oselu APC lori oro satifikeeti tun ti fe ba ona miiran yo o.
Ti e ko ba gbagbe, aini satifikeeti agunbaniro NYSC lo pon on ni dandan fun Minisita fun Oro Aje tele, Iyaafin Kemi Adeosun, lati fi ipo sile.
Oro satifikeeti NYSC ti Alhaji Adebayo Shittu ko ni naa ni APC fi ni ko wabi jokoo si nigba to fe du ipo gomina ni Ipinle Oyo.
Bayii, eni ti egbe oselu naa fa kale ni Ipinle Ogun, Ogbeni Dapo Abiodun, ni enu tun ti n kun lori awon ile iwe to ni oun lo ati satifikeeti to ye ko ni.
Won ni awon iwe eri to fi sile nigba to dije ibo senito ni odun bii merin seyin yato si eyi to ko fun ajo eleto idibo INEC bayii.
Bakan naa, won ni o jo pe ko se agunbaniro debi pe yoo ni satifikeeti re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…