Home iroyin Kii se Tinubu lo pon Adelabu ni dandan fun mi – Ajimobi
iroyin - Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - December 15, 2018

Kii se Tinubu lo pon Adelabu ni dandan fun mi – Ajimobi

Gomina Ipinle Oyo, Senito Isiaka Ajimobi, ti so pe kii se Asiwaju Bola Tinubu lo pon oludije gomina fun egbe APC, Ogbeni Bayo Adelabu, ni dandan fun oun.
O ni dipo bee, funra egbe ati bi Adelabu se ni erongba gidi lokan fun awon ara ilu lo gbe e debe.
Awon alatako egbe naa ti n so pe Tinubu lo na owoja re de Ibadan, ati pe oun to ba wu okunrin naa ni Adelabu yoo maa se.
Sugbon Ajimobi ni oro runrun ni eyi.
O ni eto idagbasoke ti oun ti n ba bo naa ni Adelabu yoo tubo gbe soke.
Banki agba, Central Bank of Nigeria, ni Adelabu ti kowe fi ipo sile, nibi to ti je igbakeji oga agba, to si wa di oludije gomina fun APC.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…