Home LÁGBO ÀRÍYÁ Femi Branch ranti oore nla ti Jide Kosoko se fun un
LÁGBO ÀRÍYÁ - December 15, 2018

Femi Branch ranti oore nla ti Jide Kosoko se fun un

Yoruba bo won ni igba iponju laa more. Ohun a ba si se lonii, itan lo maa n da lola.
Eyi lo d’Ifa fun osere pataki, Femi Branch, to fi n kan saara si agba osere Jide Kosoko, lori oore to se fun un ni odun meje seyin.
Ninu arojinle kan, Femi Branch ranti bi oun se wa ni idagunle fun odun meta leyin ti oun ni ipalara, tie se oun mejeeji ko se e gbe kaakiri mo, nigba ti oun subu lasiko ti awon wa ni lokesan fun fiimu kan.
O ni nnkan le fun oun lasiko naa, sugbon Olorun ran awon eniyan kan si oun, ti won si se iranwo malegbagbe.
Femi Branch ni ni ti Jide Kosoko, o moomo se atuse ipa kan to ye ki oun (Branch) ko ninu ere re, lona ti oun a fi le se e pelu ailera to ba oun

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…