Ilu Ibadan ti mo jokoo si gbe mi pupo – Rashidi Ayinde Merenge
Akorin fuji Pataki, Rashidi Ayinde Merenge, ti se alaye pe alubarika wo ise orin ti oun se bi o tile je pe ilu Ibadan ni oun fi se ibujokoo.
Opo olorin lo maa n sa lo si ilu Eko, tori won gba pe ibe ni ibukun wa ju.
Sugbon oro akorin ti a mo si Fuji Merege dab ii ti oga olorin awurebe, Dauda Akanmu Epo Akara, to je pe ilu Ibadan naa lo tedo si, ko to di wi pe o di oloogbe ni nnkan bii odun meedogun seyin.
Rashidi yinde so lasiko ajoro kan to waye ni ilu Ibadan laipe yii.
O ni oun ko gbe Eko ri rara.
O salaye pe bi oun ba lo sise orin ni Eko, ti oun ba sun lojo kan, ojo keji, oun ti pada si Oluyole.
Rashidi ni Olorun ko figba kan fi oun sile.
O ni ko si abala agbaye kan ti oun ko tii de korin, to si je pe laipe yii gan-an ni oun ti Canada de.
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…