Home iroyin Yahoo Yahoo: Awon omo Olabisi Onabanjo University foju ba ile ejo
iroyin - Orisirisi - December 13, 2018

Yahoo Yahoo: Awon omo Olabisi Onabanjo University foju ba ile ejo

Ajo EFCC ti gbe awon omo ile eko Olabisi Onabanjo University ati National Open University kan lo si ile ejo ni Ibadan, lori esun pe won n lu jibiti lona ti won n pe ni Yahoo Yahoo.
Mewaa ninu won ni Agboola Taiwo, Adetayo Tade Ademiluyi, Rabiu Daniel, Sokoya Oluwaseyi, Fredrick Shaibu, Oshikoya Gbolahan, Adegbola Kazeem Aina, Ademosun Opeyemi, Tosin Awobona ati Babarinde Jacob.
Ojo Monday ni won gbe awon wonyi lo siwaju Onidajo Ibrahim Watilat ti Federal High Court, ni Abeokuta.
Awon merinla miran – Adeleke Oluwamayowa, Banjo Femi, Towolawi Olanrewaju, Tijani Babatunde, Sarafadeen Abibullahi, Adebowale Abimbola, Osunkoya Korede, Mufutau Yusuf Akorede, Salisu Ajibola, Olamikan Oluwasiji, Oduwole Gbenga, Damilare Adelaja, Bakare Azeez Adebola ati Edward Ayodeji naa foju ba ile ejo ti Onidajo M. S. Abubakar ni Federal High Court 1, ni Abeokuta bakan naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…