Home LÁGBO ÀRÍYÁ Bawo ni Davido se fe se oro NYSC re si bayii leyin ti won ti le e danu?
LÁGBO ÀRÍYÁ - orisiirisii - Orisirisi - December 11, 2018

Bawo ni Davido se fe se oro NYSC re si bayii leyin ti won ti le e danu?

Opo eniyan lo n beere bayii pe kin lo ku ti akorin Davido maa se leyin ti ajo National Youths Service Corps ti le e  jade ninu rto naa.

Se yoo tun kinni naa mu ni, abi yoo gbagbe re patapata.

Awon amoye kan gba pe pelu bi o se lowo to, ti baba re naa si lowo bii sekere, ko fee nilo satifikeeti NYSC naa.

Ibeere ti won n beere ni pe: Se yoo fi wase ni tabi o fe fi se oselu?

Sibesibe, awon kan ni Olorun nikan lo mola, leyii to ja si pe aise eto agunbaniro naa le da wahala sile fun lojo iwaju. 

Funra re lo so ninu ohun kan to ko sori ero alatagba pe won ti da oun duro.

O seese pe gbogbo bo se maa n jade fokifoki, ti o maa n se ere kiri lo bi awon NYSC ninu.

Opo eniyan leru ti n ba pe boya ni Davido yoo le farabale se eto agunbaniro naa fun odun kan gbako.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…