Home orisiirisii Pastor Adeboye ranti ọjọ to yagbẹ lẹẹmetalelogun lọjọ kan soso
orisiirisii - Orisirisi - December 9, 2018

Pastor Adeboye ranti ọjọ to yagbẹ lẹẹmetalelogun lọjọ kan soso

Eni ti eegun ba n le lo ko maa roju, tori bo ti n re ara aye lo n re ara orun.
Adari agba fun soosi Redeemed Christian Church of God, Pasito EA Adeboye, so asiri kan to ya awon omo ijo lenu lojo bii meta seyin.
Nigba to n ba won soro nigba lasiko Holy Ghost Conference ti won sese se, o je ki won mo pe ko si eni ti kii re.
O ni nigba kan ti oun n se iwaasu kaakiri ni orile ede kan, ailera kan de ba oun.
Baba naa bere sii ya igbe leralera, to si je pe ko si eni kankan lodo re.
O ni laarin ojo kan, oun yagbe leemetalelogun (twenty-three times).
O ni lasiko yii ni oun to kinni naa loran.
O ni oun ba gbe owo le ara oun, ti oun sib ere adura.
O ni adura naa lo da laasigbo naa duro.
Baba Adeboye so eyi lati je ki awon omo ijo mo pe adura lo n gba, agbara ko.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…