Home LÁGBO ÀRÍYÁ Small Doctor kan ijangbon pelu awon olopaa
LÁGBO ÀRÍYÁ - December 4, 2018

Small Doctor kan ijangbon pelu awon olopaa

Omokunrin to n korin ‘Won ti gba penalty wo throwing’ ti kan ijangbon pelu awon olopaa Ipinle Eko bayii.
Won ti gba oun ati awon ore re kan mu lori esun pe won ba ibon lowo re.
Ibon sakabula ko o, eyi I awon oloyinbo n pe ni rifle ni.
Gege bi oga olopaa ipinle naa, Alagba Edgar Imohimi, se so, o ni awon okunrin naa fe digbo lu awon olopaa kan ni awon se gba won mu, ti awon si wa ka ion at iota oyinbo kan mo won lowo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…