Home Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ Rukerudo n sele ninu egbe PDP ati APC
Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - December 2, 2018

Rukerudo n sele ninu egbe PDP ati APC

Bi ibo to n bo se n sun mo etile, rukerudo n ja rain ninu egbe PDP ati APC o.
Egbinrin ote ni oro awon mejeeji, bi a se n pa okan ni omiran n ru.
Ni bayii, Goina Ipinle Rivers, Nyeson Wike, ti binu fi ipo asoju ipolongo ibo fun Atiku ni ekun Niger Delta sile.
O ni awon to n se akoso eto ipolongo naa ko ri toun ro mo, won kan n se ohun to wu won ni.
Eyi fa ki awon olori egbe naa maa sa soke ati sodo.
Ninu APC, awon agbaagba egbe naa kan ti tako Aare Muhammadu Buhari, lori bo se so pe awon ti won ni ehonu lori ibo abele egbe naa le lo sile ejo.
Awon agbaagba naa ni won so pe ohun ti egbe ba so ni abe ge, ati pe eni to ba mo pe ohun ti egbe ba se ko te oun lorun le lo si egbe oselu miran.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…