Home iroyin Idi ti mo fi pa Fatima ololufe me – Idrisu Muhammadu
iroyin - November 28, 2018

Idi ti mo fi pa Fatima ololufe me – Idrisu Muhammadu

Okunrin kan ti oruko re n je Idrisu Muhammadu ti so pe oun pa obinrin kan ti oruko re n je Fatima Isah, eni to je ololufe oun, nitori pe buroda oun n ba a ni ajosepo.
Okunrin naa to fi ipinle Niger se ibujokoo so fun awon olopaa pe oun ti maa n kilo fun Fatima ati awon obi re pe ti o ba lo fe elomiran oun maa pa a ni.
O fi kun un pe nigba ti oun ri i pe baba omo naa, Alagba Isah Efutagi, fe fun egbon oun ni Fatima lati fi se aya ni inu bi oun sodi ti oun si ran an lo sorun apapandodo.
Koda, o ni oun kilo fun egbon oun naa.
Alukoro Olopaa ni ipinle naa, Mohammed Abubakar, ni okunrin naa yo foju ba ile ejo laipe yii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…