Home Orisirisi Èmi ò ráàyè ìwádìí Fayose – Fayemi
Orisirisi - November 26, 2018

Èmi ò ráàyè ìwádìí Fayose – Fayemi

Gomina tuntun ni ipinle Ekiti, Oloye kayose Fayemi ni awon oniroyin lo fi oro wa lenu wo ni ilu Abuja. Won ni igba wo lo maa bere iwadii lori gomina ana ni ipinle naa? O ni oun ko tile fi igba kankan so pe oun maa se iwadii bi Fayose se nawo. O ni ise to wa niwaju oun ju ise iwadii lo.

O ni ipo gomina o ki n se eremode rara. O ni gbogbo nnkan ti oun fi se ipolongo ibo ti awon eniyan ipinle naa fi tu yaayaa wa dibo lo wa lokan oun lati se. O ni eni to ni nnkan se kan kan ko le ni eleyii lowo ki o tun ko ise iwadii pelu re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…