Home LÁGBO ÀRÍYÁ Bí ilé Wasiu Ayinde ṣe tóbi tó, ‘Baba ń dá gbé’ ló sì ń ṣe
LÁGBO ÀRÍYÁ - November 25, 2018

Bí ilé Wasiu Ayinde ṣe tóbi tó, ‘Baba ń dá gbé’ ló sì ń ṣe

Yamuyamuni ile ti oga onifuji, Wasiu Ayinde K1 de Ultimate ko si Ijebu Ode, ni GRA, to si je pe ile ti eniyan fi maa n gbadura si Olorun ni.
Ninu ogba nla naa, ile bii merin lo wa ninu re, eyi ti awon oloyinbo n pe ni 4-in-1.
Sugbon bi ile naa se to, obinrin Kankan ko gbe ibe pelu Wasiu Ayinde.
Akorin naa ni iyawo pupo, ti Olorun si yonda opo omo fun un.
Sugbon onikaluku awon iyawo yii lo n gbe ile ara won, ti awon kan si wa ni Eko.
Won kan lo maa n ri baba bi oro ba wa ni.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…