Home orisiirisii Make-up ni gbogbo wa fi ń gbéra – Tiwa Savage
orisiirisii - Orisirisi - November 23, 2018

Make-up ni gbogbo wa fi ń gbéra – Tiwa Savage

Akorin hip hop, Tiwa Savage ti so pe oun ko rewa to ohun ti awon eniyan maa n ri lori telivisan ati ero alatagba.
O ni lopo igba, oun maa n jawe sobi ni pelu awon ohun ti a fi n se eso sara, paapaa make-up.
O se alaye pe idi niyi ti awon eniyan ko fi gbodo maa fi gbogbo ohun ti awon gbajumo ba n se lori ero ayelujarawon social media se odiwon igbesii aye won.
O ni ohun to se pataki ju ni ki eniyan ni ewa ninu okan re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…