Èmi kọ́ ló ni dúkìá tí EFCC gbẹ́sẹ̀ lé – Fayose
Lati bi osu meji seyin bayii ni gomina tele ri ni ipinle Ekiti, Oloye Ayodele Fayose ti n waa ko pelu ajo EFCC. Awon ajo yii ni won maa n gbogun ti awon to ba n se owo tabi dukia ijoba maku-maku.
Ni igba ti awon ajo yii woo lo sotun ati si osi, won ni iwadii si n te siwaju sugbon owo Fayose ko mo ninu awon nnkankan.
Eyi lo ku ki won bere si ni gbese le awon dukia bii ile gbigbe , ile-itura, ile epo, ati awon dukia miran to see fi oju ri. Opo awon dukia ti won gbese le wa ni ipinle Ekiti.
Oloye Ayodele Fayose ni ori ti ko se ni awon ajo yii n ba ja. O ni oun ko lo ni opo awon dukia ti won gbese le. O ni sugbon to ba to asiko, gbogbo oju ni yoo rii.
Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari
Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…