Home iroyin Àwọn ọmọlẹ́yìn Ọ̀rúnmìlà fi èhónú hàn lórí hìjáàbù
iroyin - November 22, 2018

Àwọn ọmọlẹ́yìn Ọ̀rúnmìlà fi èhónú hàn lórí hìjáàbù

Awon elesin Ifa kan darapo mo awon elesin Igbagbo lojo Alaaruba, ti won si fi ehonu han si awon alase Yunifasiti ti Ibadan.
Awuyewuye be sile nigba ti awon elesin Musulumi kan, labe asia Muslim Parents Forum, ti ile iwe International College to je ti University of Ibadan, ni dandan, awon omo awon to wa ni ile iwe naa gbodo maa wo hijaabu.
Awon onIfa naa wag be ehonu lo sodo Igbakeji Olori yunifasiti naa, Ojogbon Adeyinka Aderinto.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…