Home orisiirisii Ni Ikoyi Registry, iyawo yari, ko kiisi ọkọ rẹ
orisiirisii - Orisirisi - November 21, 2018

Ni Ikoyi Registry, iyawo yari, ko kiisi ọkọ rẹ

Meriiri kan sele ni kootu to n so okunrin ati obinrin po bi aya, iyen Ikoyi Registry, ni ilu Eko, nigba ti iyawo taku pe oun ko le gbenu si bale oun lenu.
Ere ni awon to n seto igbeyawo naa koko pe e nigba ti won ni ki took-taya kiisi ara won, sugbon ti obinrin naa ni rara.
O ni esin igbagbo ko gba eniyan laaye lati maa kiisi ni ita gbangba.
Won wa lori surutu yii fun nnkan bii ogun iseju, tori obinrin naa ni oun ko ni se bee.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…