Home iroyin ‘Idi ti mo fi pa Yakubu to n ba iyawo mi sun’
iroyin - November 21, 2018

‘Idi ti mo fi pa Yakubu to n ba iyawo mi sun’

Okunrin kan, Joseph Abanda, ti so idi ti oun fi pa okunrin miran, Umaru Yakubu lo si orun osan gangan.
O ni Yakubu n ba iyawo oun sun ni, leyii ti o ni o lodi si ofin esin Islam.
Joseph ni oun ti maa n kilo fun Yakubu pe ki o ye se erekere pelu iyawo oun sugbon ko gbo.
Ipinle Niger ni isele naa ti se, ti awon olopaa ibe si ti mu Joseph sodo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…