Home iroyin Boko Haram di meji, idaamu nla ba a awon soja Naijiria
iroyin - November 21, 2018

Boko Haram di meji, idaamu nla ba a awon soja Naijiria

Ajalu ti awon alakatakiti Boko Haram n se ni orile-ede yii buru sii ni opin ose yii nigba ti a gbo pe won pa soja bii merinlelogoji.
Ipinle Bornu n laasigbo naa ti se, nibi ti iroyin ti so pe awon alakatakiti naa, ti won kun inu moto bii ogun, digbo lu ago soja kan ti won pa si Metele.
Ohun ti a gbo pe o tun mu ki ogun alakatakiti naa le sii nip e awon alagidi kan ti ya danu lara Boko Haram, ti won ti da egbe oniwahala miran sile, eyi ti won pe oruko re ni Islamic State of West Africa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…