Home orisiirisii Àwọn ọmọ Naijiria na Fashola ní pàsán ọ̀rọ̀ lórí bó ṣe sọ pé ìyípadà tí APC sèlérí kìí ṣe láarin ọdún mẹ́rin
orisiirisii - Orisirisi - November 21, 2018

Àwọn ọmọ Naijiria na Fashola ní pàsán ọ̀rọ̀ lórí bó ṣe sọ pé ìyípadà tí APC sèlérí kìí ṣe láarin ọdún mẹ́rin

Opo awon omo Naijiria ti hanyin mo Minisita fun Agbara, Ise ati Ilegbee, Ogbeni Babatunde Fashola, nigba to so pe iyipada ti egbe APC seleri kii se laarin odun merin.
O ni dipo bee, iyipada naa yo didi mimu se ti won ba dibo fun Aare Mohamamdu Buhari leekan sii ni.
O ni ohun ti ko ni dara rara nip e ki eni kan dibo fun PDP pe ki won pada si ijoba, tori eyi ti won se ko so eso rere fun Naijiria.
Oro ti minisita naa so bi opo awon to ka a lori ero alatagba ninu gidi ni.
Won ju oko oro sii, ti won n pe e ni eletan.
Koda, awon oruko ti won pe minisita naa ko see ma ate jade.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…