Ko si ohun to buru niu ki eniyan maa se yan-n-ga lori social media – Dayo Amusa
Okan lara awon onise fiimu to rinle ju, Dayo Amusa, ti so pe ko si oun to buru ninu ki gbajumo maa se afihan ohun to ba ni lori awon ero alatagba bii Instagram ati Facebook.
O ni ara okowo naa ni, tori o maa n mu ki awon ololufe iru eni bee tubo maa nifee re si.
O ni sugbon ti oun ba wa nile ara oun, iwon eku, iwon ite ni oun maa n se.
Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.
Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…