Goodluck Jonathan soro buruku si Obama
Aare ana, Dokita Goodluck Jonathan, ti juko oro si Aare orile-ede Amerika tele, Barrack Obama, lori ohun ti o so lasiko ibo ti Aare Muhammadu Buhari fi gbe Jonathan lule.
Jonathan ni ohun ti Obama so fihan pe ko nife oun, ati pe Buhari lo fe ki awn omo Naijiria dibo fun.
Jonathan fi kun un pe ko dara ki eni to ba wa nipo iru ti Obama maa fari apa kan fikan si.
Okunrin naa so oro yii lonii lasiko ti o n se ifilole iwe kan to pe ni MY TRANSITION HOURS, eyi to so iriri re lasiko ibo nla naa.
Iwe naa tun je eyi to fi gbe ojo ibi re laruge, tori oni lo pe okanlelogota odun, 61 years.
Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari
Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…