Home LÁGBO ÀRÍYÁ Jesu gba ijoba ninu aye Patience Ozokwor
LÁGBO ÀRÍYÁ - November 20, 2018

Jesu gba ijoba ninu aye Patience Ozokwor

Osere Nollywood to maa n da bi edun, to n ro bi owe, iyen Patience Ozokwor, lo ti di oniwaasu esin igbagbo bayii.
Opo eniyan maa n ro pe eni ibi tabi aje aye pelu orun ni obinrin na ni, sugbon awon to mo o deledele ni eniyan daadaa ni.
O ti wa di pasito bayii, tori o ni oun ti ba Olorun pade.
Nigba to n soro ninu iforowanilenuwo kan, o ni ohun pataki kan ti eni to ba ti di atunbi gbod se ni pe ko ni maa wo awon aso to n wo tele mo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…