Home orisiirisii Oga yunifasiti to fẹ fi ipa ba ọmọ ile iwe sun di ero atimọle
orisiirisii - Orisirisi - November 19, 2018

Oga yunifasiti to fẹ fi ipa ba ọmọ ile iwe sun di ero atimọle

A ba mo ki a maa se e, a se e tan, o di aapon.
Bee, Yoruba ni ki Olorun ma je ki oun ti yoo ko wa si wahala o wu wa je.
Adura yii ko sele ninu aye oluko agba kan ni ile eko giga Obafemi Awolowo University ,, Ile Ife tele, Ojogbon RRichard Akindele.
Gbogbo bi o se je ojogbon to, atimole lo wa bayii ni odo awon olopaa ni Osogbo.
Eyi sele leyin ti won ti le e danu ni ile iwe naa.
Opo eniyan ro pe keesi re ti pari si ibi won ti le e bi eni le aja ni, lai mo pe won a tun gbe e lo sile ejo.
Omo ile iwe naa kan tele, Monica Osagie, lo tu Akindele sita nigba to ni ko je ki o ba oun sun ko le paasi ise kan to n ko oun ati awon akegbe re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…