Home LÁGBO ÀRÍYÁ Peter Okoye ni ki iya oun to ku, o gbadura fun iyawo oun
LÁGBO ÀRÍYÁ - November 18, 2018

Peter Okoye ni ki iya oun to ku, o gbadura fun iyawo oun

Akorin Peter Okoye, to je okan lara awon ibeji PSquare tele, ti so pe aheso oro lasn ni wi pe iya oun ko fowo si igbeyawo oun pelu Lola.
O ni dipo bee, inu iya naa dun si obinrin naa, to si sure fun un ko to teri gbaso.
Ninu oro pataki tii PSquare so lati se ayesi fun aya re lori ojo ibi to se, o ni nigba ti ara iya oun ko ya, Lola lo wa pelu re, to n toju re losan-an loru.
O ni eyi mu ki inu iya naa dun, to si sure fun un gidigidi.
Peter ni ife ti oun ni si Lola po pupo, tori Olorun lo ran an si oun, ti oun naa si fi gbogbo nnkan nifee oun naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara Orẹ Òtítọ́jù Egbìnrìn ọ̀tẹ̀ bí a ṣe ń pà…