Home Orisirisi Emi o dije du ipo oselu mo – Ogbeni Aregbesola
Orisirisi - November 18, 2018

Emi o dije du ipo oselu mo – Ogbeni Aregbesola

Gomina ipinle Osun, Ogbeni Rauf Aregbesola ni ti saa ti o n lo yi ba ti pari. Oun ko dije du ipo oselu kankan mo. O ni awon ebi oun nilo oun nitori pe ojo ti n pa igun bo lati ojo to ti pe. Oun ti se komisona odun mejo ni ipinle Eko ki oun tun to wa je gomina ni ipinle Osun.

O ni gbogbo awon ipo yii je ipo ti ko fi aaye itoju ebi sile. O ni ko si ooto kankan nilo iroyin eleje ti awon kan n gbe kiri pe oun fe dije du ipo Seneto ni agbegbe Alimoso to wa ni ipinle Eko. O ni Ilesa tii se ilu oun ni oun maa pada si ti saa gomina yii ba ti pari.

Ilu Osogbo tii se oluulu ipinle Osun ni gomina Aregbesola ti n salaye yii fun awon oniroyin.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…