Owo awon olopaa tẹ ole ONE CHANCE ni Abuja
Owo ti te awon ole meta kan ti won maa n ja awon eniyn ti won ba gbe sinu moto ero lole.
Awon naa ni a mo si ‘one chance’, tori bi won se maa n tan ero wo inu moto, nigba ti won ba n pariwo, ‘one chance, one chance’, ti won yo maa so pe ero kan soso lo ku ki moto o kun, ki eni ti oju ba n kan sis are wole.
Awon ole ti owo te naa ni Onyebuchi Ifeanyichukwu, Anthony Sunday, Sanni Bala ati Usman Ali.
Agbegbe si Kubwa ati Zuba ni won ti n da awon eniyan loro ki ow awon agbofinro to ba won.
Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara
Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara Orẹ Òtítọ́jù Egbìnrìn ọ̀tẹ̀ bí a ṣe ń pà…