Home iroyin Ajalu ni Ikorodu: Won ba oku ọmọ meji ninu freezer
iroyin - November 13, 2018

Ajalu ni Ikorodu: Won ba oku ọmọ meji ninu freezer

Awon olopaa Ipinle Eko ti n sise lori atimo ohun to sele loru ana ni ilu Ikorodu, to mu ki omode meji kan dede ku laarin oru.
Ohun to tun n ru awon ara ilu naa loju ni pe inu ero amomitutu, iyen freezer, ni won ni won ti ba oku awon omo naa.
Baba awon omo yii, Ogbeni Michael Ede, lo lo ke gbajare ba awon olopaa, nigba to ni oun ba oku awon omo naa ninu feezer, leyin ti awon jo sun ni ale ana.
Awon omo naa ni Emma ati Darasimi, ti ekinni je omo odun mefa, ati ekeji, omo odun merin.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…