Ologun Naijiria segun Boko Haram ni Bornu
Awon jagunjagun orileede Naijiria ti gbogbo aye mo si “lafia dole” tun gba ona eburu yo lati segun awon Boko Haram to n se awon eniyan agbegbe naa bi ose se n soju.
Abule meje otooto ni awon ologun yi ti le awon ajajagbara naa ni ale doju bole. Eyi tun mu alaafia ba awon agbegbe naa.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…