Home iroyin ọmọ Ibadan ni okunrin to bẹ sinu omi ni Third Mainland Bridge
iroyin - November 5, 2018

ọmọ Ibadan ni okunrin to bẹ sinu omi ni Third Mainland Bridge

Imole si tan si iru eni ti okunrin kan to be sinu odo Osa lati ori afara moto nla Third Mainland Bridge ni Eko je.
Oruko re ni Rauf Oladejo, eni to je omo bibi ilu Ibadan.
Ibadan naa ni awon ebi re wa, ti iyawo re n je Iyaafin Zainab Oladejo.
Omo mejo lo fi sile saye lo.
Ile ise Feedral Radio Corporation , awon ni Radio Nigeria, lo ti je direba ki o to pa ara re.
Ninu iroyin kan ti iwe iroyin THE PUNCH gbe jade lonii, iyawo okunrin naa se alaye pe aare Kankan ko se bale oun.
O ni eni to feran alaafia ni, ti ko si ba eni Kankan ja.
Okan lara awon omo re naa, Sherif Oladejo, ni oju owo kop on baba oun ju ti egbe re lo, ati pe lojo to ku, won ba egberun mewaa naira – N10,000 – lapo re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…