Home Orisirisi O se! Seun Egbegbe si wa ni atimole
Orisirisi - November 5, 2018

O se! Seun Egbegbe si wa ni atimole

Leyin bii odun meji ti awon olopaa ti gbe okunrin alariya kan, Seun Egbegbe, ju si ahamo, atimole naa lo si wa ni ilu Eko o.
Koda, nigba ti ile ejo gba beeli re, o jo pe ko ri eniyan duro fun un.
Esun jibiti ni won fi kan Seun Egbegbe, paapaa lori bi won ni o se n fi ona modaru ji owo awon Mola ti won n se pasi paaro owo ile okere si naira.
Egbegbe tun se agabako ofin nigba ti awon kan ti won n ta foonu ni Ikeja so pe o fe ji awon foonu nla nla kan lo.
Sugbon sa o, a gbo pe won yoo da Egbegbe pada sile ejo lonii.
Bi o tile je pe opo eniyan ti gbagbe nipa okunrin naa, orin igbalode hip hop kan, nibi ti akorin naa ti maa n so pe ‘Je n fun won legbegbe’, maa n ran won leti.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…