Home Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ PDP fi Buhari se yẹyẹ lori satifkeeti to sẹsẹ gba
Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - November 2, 2018

PDP fi Buhari se yẹyẹ lori satifkeeti to sẹsẹ gba

Egbe alatako, PDP, ti yo suti ete si Aare Muhammadu Buhari lori satifikeeti to sese gba lati owo ajo eleto idanwo West African Examination Council.
Ninu atejade kan ti abenugan egbe naa, Ogbeni Kola Ologbodiyan, gbe jade, o ni ateyinkogbon aketiaja ni oro satifikeeti naa, ti aja ti won ti ge eti re sese wa n fi obe pamo nigba t eti naa ti n ran bi okooto nile.
O ni bawo lo se je pe igba ti ibo ku die ni won sese gbe iwe eri naa jade?
O ni o se je pe won tun le foto Buhari mo iwe eri naa, to si je pe foto pelebe naa kii se ti omode, sugbon ti igba ti Buhari ti dagba ni?

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…