Buhari sọrọ lori satifikeeti WAEC to sẹsẹ gba
O jo pe inu Aare Muhammadu n dun sinkin lori bi owo re se te satifikeeti WAEC re lonii.
Boya eebu ti opo eniyan ti n bu u tele nigba ti ko tii ri satifikeeti naa mu sita lo je ki inu re maa dun bee.
Nigba ti o n soro lori satifikeeti ti ajo WAEC fun un lonii, o so pe odun 1961 ni oun se idanwo naa.
O ni Oloogbe Sheu Yarduah je okan lara awon ti awon jo wa ni kilaasi.
Bakn naa, o ni bi oun ko ba ni iwe eri naa ni, oun ko ba ti ni anfaani lati kekoo ni Defence Services Staff College in India in 1973 to wa ni orile-ede India ati United States Army College to wa ni Amerika.
Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari
Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…