Home Orisirisi Mo sese bere ere sise ni – Shola Sobowale
Orisirisi - October 28, 2018

Mo sese bere ere sise ni – Shola Sobowale

Gbajugbaja onifiimu, Shola Shobowale, ti so pe pelu itesiwaju to ba oun lenu ise fiimu ni laipe yii, o ti wad a oun oju pe oun sese bere aseyori ni.
O ni nigba ti oun se ere Toyin Tomato, irawo oun tan gidi. O ni nigba ti oun tun kopa nnu fiimu Wedding Party, opo eniyan tun ko haa, sugbon o je oun iyanu nla fun oun pe idan orita sese tun fe jade fun oun ninu fiimu King of Boys ti Kem Adetiba sese fe gbe jade.
Nipa idi eyi, Sobowale ni oun ti wa gba pe oun sese n meye bo lapo ni.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…