Home LÁGBO ÀRÍYÁ Toyin Aimakhu laali awon awon to ni o fe se igbeyawo pelu osere fiimu
LÁGBO ÀRÍYÁ - October 23, 2018

Toyin Aimakhu laali awon awon to ni o fe se igbeyawo pelu osere fiimu

Gbajugbaja elere fiimu, Toyn Abrahams, to n je Toyin Aimakhu tele, ti so pe iro funfun balau ni awon to so pe oun n pete igbeywo pelu osere fiimu kan n pa.
O ni onisokuso ati alailooto ni won.
O ni oun ko ni duro de Saliu elenu-gboro Kankan ti oun ba fe se igbeyawo, oun maa kede re faraye funra oun ni.
Toyin ni ko si oun toju ko riri ninu ki okunrin ati obinrin jo maa sise po, eugbon ko tumo sip e won fe fi oruka sira won lowo ni.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…