Home Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ Fayose se ‘stomach infrastructre’ ni atimole
Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - October 23, 2018

Fayose se ‘stomach infrastructre’ ni atimole

Gomina Ipinle Ekiti tele, Ogbeni Ayodele Fayose, ni a gbo pe o ti n sise alaanu ara Samaria ninu atimole ti ajo EFCC gbe e si bayii.
EFCC gbe Fayose lo sile ejo lori esun pe o se owo to le ni bilionu kan aabo naira basubasu.
A gbo pe o n fun awon elewon to ba ni atimole ni owo ati ounje, eyi to tumo si pe elewon logaa loooto.
Fayose ni awon eniyan mo eto iselu ‘stomach infrastruture’, nibi to ti maa n pin ounje ati ohun elo fun awon eniyan, ti oun naa yoo si maa ba won jeun ni buka.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àmọ̀tẹ́kùn yẹ kó di ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ láìpẹ́ – Akeredolu

Àmọ̀tẹ́kùn yẹ kó di ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ láìpẹ́ – Akeredolu Ọrẹ Òtítọ́jù Sé wọ́n ní a kìí wí sí…