Home iroyin Buhari seranti Tunde Idiagbon
iroyin - October 23, 2018

Buhari seranti Tunde Idiagbon

Aare Muhammadu Buhari ti ranti igbakeji re nigba kan, Ogagun Tunde Idiagbon.
Buhari ati okunrin to gbona bii Elegun Sango naa ni won jo sejoba nigba ti won je ologun, leyin ti won gba ijoba lowo Sheu Shagari.
Nigba ti awon oloselu kan lati Ipinle Kwara se abewo si Buhari ni Abuja, o se apejuwe Idiagbon gege bii eni to see fokan tan, to si nifee Naijiria tokantokan.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…